Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Àwọn àbá tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ lórí ọ̀ràn yìí wà nínú àwọn àpilẹ̀kọ bí “Ìfìbálòpọ̀-Fòòró-Ẹni—Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dáàbòbo Ara Mi?” àti “Kí Ni Mo Lè Ṣe Láti Mú Kí Ọ̀rẹ́kùnrin Mi Dẹ́kun Fífìyà Jẹ Mí ?” tí wọ́n jáde nínú abala “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . ,” nínú àwọn ìtẹ̀jáde wa ti August 22, 1995, àti July 8, 2004.