Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nígbà míì, èèyàn lè kárùn téèyàn bá ń tọ́jú ẹyẹ tára ẹ̀ ò yá tàbí tó ṣèṣe, ó sì lè máà bá òfin àdúgbò yẹn mu.