Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Arákùnrin Efrem Platon kú ní July 28, ọdún 2005, nígbà tí iṣẹ́ ń lọ lọ́wọ́ lórí àtigbé àpilẹ̀kọ yìí jáde.