Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a “Nánò” tó bẹ̀rẹ̀ nànómità, wá látinú èdè Gíríìkì tó túmọ̀ sí aràrá, ó sì túmọ̀ sí “ìdá kan nínú bílíọ̀nù.”