Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ó ṣàyẹ̀wò Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Gẹ̀ẹ́sì, ó tún ṣàyẹ̀wò àwọn ìtumọ̀ míì, àwọn sì ni Bíbélì The Amplified New Testament, The Living Bible, The New American Bible With Revised New Testament, New American Standard Bible, The Holy Bible—New International Version, The New Revised Standard Version, The Bible in Today’s English Version, àti Bíbélì King James.