Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó bá ṣẹlẹ̀ pé nígbà ìbímọ ẹ̀mí ọmọ tàbí ti ìyá wà nínú ewu, àwọn tọ́ràn bá kàn gbọ̀ngbọ̀n ló máa pinnu ohun tí wọ́n máa ṣe. Àmọ́, irú ìpinnu bẹ́ẹ̀ kì í sábàá wọ́pọ̀ nítorí ibi tí ìtẹ̀síwájú ti bá ìtọ́jú ìṣègùn dé ní ọ̀pọ̀ ilẹ̀.