Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó o bá fẹ́ káwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wá máa kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ lákòókò tó tẹ́ ẹ lọ́rùn àti níbi tó o fẹ́, o lè kàn sí Gbọ̀ngàn Ìjọba wọn ládùúgbò tàbí kó o kọ̀wé sí ọ̀kan lára àwọn àdírẹ́sì tá a tò sí ojú ewé 5 nínú ìwé ìròyìn yìí. Tàbí kó o kàn sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì nípa lílo àdírẹ́sì ìkànnì wọn, ìyẹn www.watchtower.org.