Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó o bá ń finú han àwọn òbí rẹ, síbẹ̀ tí wọn ò fọkàn tán ẹ, fara balẹ̀, kó o sì fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ ṣàlàyé bọ́rọ̀ náà ṣe rí lára rẹ fún wọn. Tẹ́tí sílẹ̀ dáádáá kó o lè mọ ohun tó ń kọ wọ́n lóminú, kí ìwọ náà sì rí i pé o ò ṣe ohunkóhun láti dá kún ìṣòro yẹn.—Jákọ́bù 1:19.