Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú Bíbélì, kì í ṣe ìbálòpọ̀ nìkan ni ọ̀rọ̀ náà “àgbèrè” ń tọ́ka sí, àmọ́ ó tún kan àwọn nǹkan míì tí àwọn tí kì í ṣe tọkọtaya máa ń ṣe, irú bíi fífọwọ́ pa èyà ìbímọ ẹlòmíì, fifi ẹnu lá ẹ̀yà ìbímọ ẹlòmíì tàbí bíbá ẹlòmíì lò pọ̀ ní ihò ìdí. Tó o bá fẹ́ àlàyé púpọ̀ sí i, wo ìwé Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá 2, ojú ìwé 42 sí 47.