Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Fún ìsọfúnni síwájú sí i, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . Ṣé Mo Ti Sọ Àwọn Ohun Tó Ń Gbé Ìsọfúnni Jáde Di Bárakú?” nínú Jí! April–June 2011. Kó o sì túbọ̀ kíyè sí ìsọfúnni tó wà nínú àpótí tó wà lójú ìwé 26, ìyẹn “Ìkànnì Táwọn Èèyàn Ti Ń Fọ̀rọ̀ Jomi Toro Ọ̀rọ̀ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì Di Bárakú fún Mi.”