Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí Bíbélì bá sọ pé “àkókò tí ó lọ kánrin”, gbogbo ìgbà kọ́ ló máa ń túmọ̀ sí títí láé. Ó tún lè túmọ̀ sí àkókò gígùn tàbí àkókò tí a kò mọ ìgbà tó máa dópin.