Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àwọn èdè tí wọ́n fi kọ Bíbélì ní ìpilẹ̀ṣẹ̀, ìyẹn èdè Hébérù àti Gíríìkì, nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méje [7,000] ìgbà ni orúkọ Ọlọ́run fara hàn nínú Bíbélì. Ṣùgbọ́n, ó ṣeni láàánú pé, orúkọ oyè tí Ọlọ́run ní ni ọ̀pọ̀ ìtúmọ̀ Bíbélì tó wà lóde òní lò dípò orúkọ mímọ́ rẹ̀.