Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Kì í ṣe pé àwọn òkú máa ń gbé ara míì wọ̀ tí wọ́n á sì lọ máa gbé ní ibòmíì, ṣùgbọ́n ńṣe ni wọ́n ń ‘sùn,’ tàbí pé “wọn kò mọ nǹkan kan rárá,” títí dìgbà tí wọ́n máa jíǹde lọ́jọ́ iwájú.—Jòhánù 5:28, 29; 11:11-13; Oníwàásù 9:5.