Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àmọ́ ọ̀pọ̀ èèyàn tó wà lóde òní náà lè jẹ́ àwòkọ́ṣe gidi fún wa. Lára irú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ ni àwọn òbí wa, àwọn ẹ̀gbọ́n tàbí àbúrò wa, àwọn tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jinlẹ̀ nínú wọn lára àwọn tá a jọ wà nínú ìjọ Kristẹni tàbí ẹlòmíì tó jẹ́ àpẹẹrẹ àtàtà tó o mọ̀ dáadáa tàbí tó o ti kà nípa rẹ̀.