Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ọ̀nà míì tó o lè gbà ṣe ohun tá a sọ yìí ni pé kó o kọ́kọ́ yan ẹni tó o bá fẹ́ fi ṣe àwòkọ́ṣe. Lẹ́yìn náà, béèrè lọ́wọ́ ara rẹ pé: ‘Irú ìwà wo gan-an ló mú kí ẹni yìí wù mí?’ Fi ẹni yẹn ṣe àwòkọ́ṣe rẹ, kó o sì máa sapá láti fara wé ìwà tó wù ọ́ lára rẹ̀.