Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ohun tí Bíbélì ń sọ kò túmọ̀ sí pé kí àwọn òbí máa lu ọmọ wọn nílùkulù tàbí kí wọ́n bà wọ́n nínú jẹ́ o. (Éfésù 4:29, 31; 6:4) Torí kí wọ́n lè kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ ló ṣe ní kí wọ́n máa bá wọn wí, kò túmọ̀ sí pé kí àwọn òbí máa kanra mọ́ àwọn ọmọ wọn.