Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Òótọ́ ni pé Plato ló tan ẹ̀kọ́ tó dá lórí bí ẹ̀mí ṣe ń lọ síbìkan lẹ́yìn téèyàn bá kú kálẹ̀, òun kọ́ ló kọ́kọ́ gba ẹ̀kọ́ yìí gbọ̀. Ó pẹ́ tí ẹ̀kọ́ yìí ti wà lóríṣiríṣi nínú ẹ̀sìn àwọn kèfèrí àti nínú ẹ̀sìn àwọn ará Íjíbítì àti Bábílónì.