Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bíbélì sọ pé àwọn tó ti kú dà bí ẹni tó sùn. Wọ́n ń dúró de àjíǹde. (Oníw. 9:5; Jòh. 11:11-14; Ìṣe 24:15) Tó bá jẹ́ pé ẹ̀mí tàbí ọkàn wọn kò kú, a jẹ́ pé kò sí àjíǹde nìyẹn.