Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ọ̀pọ̀ àwọn tí wọ́n fipá bá lò pọ̀ sábà máa ń mọ ẹni tó ṣe iṣẹ́ ibi yẹn. Wo àkòrí tá a pè ní, “Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Kó Sọ́wọ́ Àwọn Tó Ń Fipá Báni Lò Pọ̀?” ní ojú ìwé 228 nínú ìwé Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá 1. O lè rí ìwé náà lórí ìkànnì www.jw.org.