Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọlọ́run gbà kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ máa jagun kí wọ́n lè dáàbò bo ìlú wọn. (2 Kíróníkà 20:15, 17) Àmọ́, gbogbo ìyẹn yí pa dà lẹ́yìn tí Ọlọ́run wọ́gi lé májẹ̀mú tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá, tó sì dá ìjọ Kristẹni tí kò ní ààlà ilẹ̀ sílẹ̀.