Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìgbà míì wà tó jẹ́ pé àìlera ló máa ń mú kéèyàn ní èrò òdì, ó sì yẹ kí ẹni tó bá ní irú ìṣòro yìí lọ rí dókítà fún ìtọ́jú tó yẹ. Ìwé ìròyìn Jí! kò sọ irú ìtọ́jú pàtó tó yẹ kẹ́nì kan gbà. Kálukú ló máa pinnu irú ìtọ́jú tó bá ipò rẹ̀ mu.