Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Oríṣiríṣi ọ̀nà tá a máa jíròrò nípa àwọn ọkùnrin àti obìnrin lè má bá bọ́rọ̀ ṣe máa ń rí lára gbogbo ọkọ àti ìyàwó mu. Àmọ́, àwọn ìlànà tá a máa jíròrò lè ran tọkùnrin tobìnrin tó ti ṣègbéyàwó lọ́wọ́ láti túbọ̀ lóye ẹnì kejì wọn, kí wọ́n sì jọ máa sọ̀rọ̀ lọ́nà tó dáa.