Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ìrètí àjíǹde tún lè mú kéèyàn ní àlááfíà ọkàn. Wo “Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé” nínú Ilé Ìṣọ́ April 15, 2009. Àpilẹ̀kọ náà sọ àwọn ìlànà tó fi hàn pé ó ṣeé ṣe kí àwọn ọmọ tó kú sínú oyún ní àjínde.