Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Kódà, ọ̀rọ̀ Hébérù àti Gíríìkì ìpilẹ̀ṣẹ̀ tá a lò fún “áńgẹ́lì” túmọ̀ sí “ìránṣẹ́.”