Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó o bá ṣì ń tọ́ ọmọ lọ́wọ́, má gbàgbé pé “ara kan” ni ìwọ àti ẹnì kejì rẹ. (Máàkù 10:8) Ọkàn àwọn ọmọ máa ń balẹ̀ gan-an tí wọ́n bá rí i pé àárín àwọn òbí wọn gún dáadáa.