Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àmọ́ ṣá o, láwọn ibì kan, irú ẹ̀rọ tí wọ́n ń lò nínú ilé wọn lè gba kí wọ́n ṣílẹ̀kùn àti wíńdò sílẹ̀ kí afẹ́fẹ́ gbẹ̀mígbẹ̀mí má bàa dé wọn mọ́lé. Torí náà, rí i pé o tẹ̀ lé ìtọ́ni tó wà lára ẹ̀rọ tó o rà sílé rẹ.