Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìfiwéra tí wọ́n ṣe nípa ojú àti camera obscura yìí kò fi bẹ́ẹ̀ yé àwọn èèyàn nígbà yẹn ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti Yúróòpù, àfìgbà tí ọ̀gbẹ́ni kan tó ń jẹ́ Johannes Kepler ṣàlàyé rẹ̀ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kẹtàdínlógún.