ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

b Ẹkunrẹrẹ ijiroro nipa itilẹhin ẹgbẹ alufaa fun Ogun Agbaye I ni a fifunni ninu iwe naa Preachers Present Arms, lati ọwọ́ Ray H. Abrams (New York, 1933). Iwe naa wi pe: “Awọn alufaa fun ogun naa ní ijẹpataki tẹmi ati isunniṣe onigbonara rẹ̀. . . . Ogun naa fúnraarẹ̀ jẹ́ ogun mímọ́ lati gbé Ijọba Ọlọrun lori ilẹ̀-ayé ga. Lati fi ẹmi ẹni lélẹ̀ nitori orilẹ-ede ẹni jẹ́ lati fi i fun Ọlọrun ati Ijọba Rẹ̀. Ọlọrun ati orilẹ-ede wá di bakan naa. . . . Awọn ara Germany ati awọn Orilẹ-Ede Aládèéhùn Ifọwọsowọpọ jẹ́ bakan naa ninu ọran yii. Ìhà kọọkan gbà pe oun nikanṣoṣo lo ni Ọlọrun . . . Ọpọ julọ ninu awọn ẹlẹkọọ isin ni wọn kò ní iṣoro eyikeyii ní gbigbe Jesu ka apa iwaju patapata ninu ija ti ó kira julọ ti ń ṣamọna awọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun rẹ̀ lọ si ijagunmolu. . . . Ṣọọṣi tipa bayii di apakan timọtimọ fun eto-igbekalẹ ogun. . . . Awọn aṣaaju [ṣọọṣi] kò fi akoko kankan ṣofo ní ṣiṣeto ara wọn jọ daradara bi akoko bá tó fun ogun. Laaarin wakati mẹrinlelogun lẹhin ipolongo ogun, Igbimọ Apapọ Awọn Ṣọọṣi Kristi ní America gbe awọn iwewee kalẹ fun ifọwọsowọpọ kikunrẹrẹ julọ. . . . Ọpọ ninu awọn ṣọọṣi tun ṣe rekọja ohun ti a beere lọwọ wọn. Wọn di ibudo igbanisiṣẹ fun wiwọ iṣẹ ologun.”​—⁠Oju-iwe 53, 57, 59, 63, 74, 80, 82.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́