Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Wúrà ni wọ́n fi ṣe àwọn ohun ọ̀ṣọ́ inú tẹ́ńpìlì Sólómọ́nì tàbí tí wọ́n fi bò wọ́n lára. Àmọ́ bàbà ni wọ́n lò fún àwọn ohun tó wà nínú àgbàlá.—1 Àwọn Ọba 6:19-23, 28-35; 7:15, 16, 27, 30, 38-50; 8:64.