Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ nínú èdè Hébérù náà, C. F. Keil, kọ̀wé nípa Dáníẹ́lì 5:3 pé: “LXX. (Bíbélì Greek Septuagint) kọ̀ láti mẹ́nu kan àwọn obìnrin níhìn-ín àti ní ẹsẹ ìkẹtàlélógún pẹ̀lú, ní ìbámu pẹ̀lú àṣà àwọn ará Makedóníà, àwọn Gíríìkì àti ti Róòmù.”