Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e Àwọn òpìtàn kan ti sọ pé èyí jẹ́ kí a mọ ìdí tí Alẹkisáńdà fi yọ́nú gan-an sí àwọn Júù, tí wọ́n ti fìgbà pípẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ àwọn ará Páṣíà. Orí ìgbétásì láti pa gbogbo ọ̀rẹ́ ilẹ̀ Páṣíà run ni Alẹkisáńdà wà ní ìgbà yẹn.