Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b “Bẹliteṣásárì” túmọ̀ sí “Dáàbò Bo Ìwàláàyè Ọba.” Ó ṣeé ṣe kí “Ṣádírákì” túmọ̀ sí “Àṣẹ Aku,” ọlọ́run òṣùpá ti àwọn ará Sumer. Ó dà bí pé Méṣákì tọ́ka sí ọlọ́run àwọn ará Sumer, Àbẹ́dínígò sì túmọ̀ sí “Ìránṣẹ́ Négò,” tàbí Nébò.