Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ọ̀rọ̀ Gíríìkì tí a túmọ̀ sí “fífi àlùmọ́ọ́nì ìgbésí ayé ẹni hàn sóde lọ́nà ṣekárími” ni a·la·zo·niʹa, tí wọ́n ṣàlàyé pé ó jẹ́ “ìṣefọ́nńté asán, aláìtọ́, tó máa ń jẹ́ kéèyàn gbẹ́kẹ̀ lé àwọn nǹkan ti ayé, bí ẹni pé ayé tọ́ lọ bí ọ̀pá ìbọn.”—The New Thayer’s Greek-English Lexicon.