Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lo gbólóhùn náà, “ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òdodo,” nítorí pé ọ̀rọ̀ atọ́ka ohun púpọ̀ ló wà ní ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ní èdè Hébérù. Ńṣe ni wọ́n lo ọ̀rọ̀ atọ́ka ohun púpọ̀ níhìn-ín láti fi gbé bí òdodo Jèhófà ṣe pọ̀ gidigidi tó yọ.