Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Lédè Hébérù, àkànlò èdè ni “wúńdíá ọmọbìnrin Bábílónì” jẹ́, Bábílónì tàbí àwọn olùgbé Bábílónì ni wọ́n sì ń lò ó fún. “Wúńdíá” sì ni nítorí kò tíì sí aṣẹ́gun kankan tó fi í ṣèjẹ látìgbà tó ti di agbára ayé.