Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ìwé Nabonidus and Belshazzar, tí Raymond Philip Dougherty kọ, sọ pé lóòótọ́ Àkọsílẹ̀ Ìtàn Nábónídọ́sì sọ pé ńṣe làwọn tó ṣígun wá sí Bábílónì kàn wọ̀lú “láìsí ìjà,” àmọ́ ọmọ Gíríìkì òpìtàn náà, Sẹ́nófọ̀n, fi hàn pé ó ṣeé ṣe kí iye ẹ̀mí tó ṣòfò máà kéré.