Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Wòlíì Míkà pé Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ní ibi “tí ó kéré jù láti wà lára àwọn ẹgbẹẹgbẹ̀rún Júdà.” (Míkà 5:2) Síbẹ̀, ìlú Bẹ́tílẹ́hẹ́mù kékeré yìí ni a dá lọ́lá pé kí ó jẹ́ ibi tí wọ́n ti máa bí Mèsáyà.