Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e Lọ́dún 1918, ìpíndọ́gba iye àwọn tó ń kópa nínú iṣẹ́ ìwàásù ọ̀rọ̀ náà lóṣooṣù kò tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rin.