Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nínú àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì “orúkọ tuntun” lè dúró fún ipò tàbí àǹfààní tuntun kan.—Ìṣípayá 2:17; 3:12.