Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d A tún lè bẹ̀rẹ̀ ẹsẹ yìí báyìí pé: “Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí rántí.” (Aísáyà 63:11, àlàyé etí ìwé, NW) Ṣùgbọ́n, èyí kò fi dandan túmọ̀ sí pé Jèhófà ni ẹni tó ń rántí nǹkan wọ̀nyẹn. Bí nǹkan ṣe rí lára àwọn èèyàn Ọlọ́run fúnra wọn ni ọ̀rọ̀ tó tẹ̀ lé e ń sọ, kì í ṣe bí ó ṣe rí lára Jèhófà fúnra rẹ̀. Ìyẹn ni ìwé Soncino Books of the Bible fi túmọ̀ ọ̀rọ̀ yẹn báyìí pé: “Ìyẹn làwọn èèyàn Rẹ̀ fi wá rántí àwọn ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn.”