Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bíbélì sábà máa ń lo ètè láti fi ṣàpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ tàbí èdè. Ó ṣe tán, ọ̀rọ̀ ẹnu àwa ẹ̀dá èèyàn aláìpé ló sábà máa ń sún wa dẹ́ṣẹ̀. Torí náà, gbólóhùn náà, “ọkùnrin tí ètè rẹ̀ kò mọ́” bá a mu gan-an.—Òwe 10:19; Jémíìsì 3:2, 6.