ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Ọ̀pọ̀ ìgbà ni ìjì máa ń dédé jà lójú Òkun Gálílì. Ìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀ ni pé ibi tí òkun náà wà lọ sísàlẹ̀ gan-an (ó fi nǹkan bí ọgọ́rùn-ún méjì (200) mítà lọ sísàlẹ̀ ju ojú òkun), afẹ́fẹ́ ibẹ̀ sì sábà máa ń gbóná ju tàwọn òkun míì lọ. Torí náà, ìgbàkigbà ni ojú ọjọ́ lè yí pa dà níbẹ̀. Atẹ́gùn líle tó ń rọ́ wá láti orí Òkè Hámónì tó wà lápá àríwá máa ń fẹ́ lọ sí Àfonífojì Jọ́dánì. Torí náà, ojú ọjọ́ ti lè pa rọ́rọ́ tẹ́lẹ̀, àmọ́ kí ìjì líle bẹ̀rẹ̀ sí í jà lẹ́yìn ìṣẹ́jú bíi mélòó kan.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́