Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Sáàmù 86:5 sọ pé Jèhófà jẹ́ “ẹni rere” àti pé ó “ṣe tán láti dárí jini.” Nígbà tí wọ́n ń tú ọ̀rọ̀ inú sáàmù yìí sí èdè Gíríìkì, ọ̀rọ̀ tí wọ́n lò fún “ṣe tán láti dárí jini” ni e·pi·ei·kes.ʹ Ọ̀rọ̀ yìí kan náà ni wọ́n máa ń lò fún kéèyàn “fòye báni lò.”