Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àmọ́, ní Sáàmù 103:13 wọ́n lo ọ̀rọ̀ Hébérù náà ra·chamʹ fún irú àánú, tàbí ojú àánú tí bàbá kan ní sáwọn ọmọ ẹ̀.