Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Èyí ò túmọ̀ sí pé Sátánì ló ń fúnra rẹ̀ darí àwọn to bá ta kò ọ́. Àmọ́ Sátánì ni Ọlọ́run ayé yìí, gbogbo ayé ló sì wà lábẹ́ agbára rẹ̀. (2 Kọ́ríńtì 4:4; 1 Jòhánù 5:19) Nítorí náà, ó ṣeé ṣe káwọn kan ta kò ọ́ níwọ̀n bí ọ̀pọ̀ jù lọ ò ti nífẹ̀ẹ́ sí gbígbé ìgbé ayé tó ń múnú Ọlọ́run dùn.