Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀dọ́ ni Dáfídì, Bíbélì tiẹ̀ pè é ní “ọmọdékùnrin” nígbà tó pa Gòláyátì, kò sì ju nǹkan bí ọmọ ọgbọ̀n ọdún lọ nígbà tí Jónátánì kú. (1 Sámúẹ́lì 17:33; 31:2; 2 Sámúẹ́lì 5:4) Nǹkan bí ọmọ ọgọ́ta ọdún ni Jónátánì nígbà tó kú, èyí tó fi hàn pé ó fi nǹkan bí ọgbọ̀n ọdún ju Dáfídì lọ.