Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c “Àwọn ohun tó ń mọ́kàn fà sí ìṣekúṣe” tá à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ níbí yìí túmọ̀ sí àwòrán, ìwé, ọ̀rọ̀ orin, tàbí ọ̀rọ̀ ẹnu tó máa ń mú kéèyàn fẹ́ láti ní ìbálòpọ̀. Ó sì tún lè jẹ́ àwòrán tó ń fàwọn kọ́lọ́fín ara hàn, tàbí ti àwọn èèyàn tó ń bára wọn lò pọ̀ bí ajá.