Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Bó o bá ń fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i nípa ọwọ́ tó yẹ kó o fi mú ìbátan rẹ tí wọ́n yọ lẹ́gbẹ́, wo ìmọ̀ràn tá a gbé karí Ìwé Mímọ́, èyí tó wà nínú Ilé-ìṣọ́nà ti April 15, 1988, ojú ìwé 26 sí 31, àti January 15, 1982, ojú ìwé 26 sí 31.