Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí òbí ẹ tó ń mutí lámujù bá ń fìyà jẹ ẹ́, ohun tó máa dáa jù ni pé kó o wá ìrànlọ́wọ́ lọ. Finú han àgbàlagbà kan tó o fọkàn tán. Bó bá sì jẹ́ pé Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni ẹ́, o lè sọ fún alàgbà kan nínú ìjọ yín tàbí Kristẹni kan tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú ẹ̀.