Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ibi àkọ́kọ́ nìyí lára àwọn ibi tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ogún (20) tí ìwé Ìṣe ti sọ̀rọ̀ nípa àwọn áńgẹ́lì ní tààràtà. Ìṣe 1:10 ti kọ́kọ́ sọ̀rọ̀ nípa wọn lọ́nà tí kò ṣe tààràtà nígbà tó sọ pé “ọkùnrin méjì tó wọ aṣọ funfun.”